Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Gehasi lepa Naamani. Nigbati Naamani ri ti nsare bọ̀ lẹhin on, o sọ̀kalẹ kuro ninu kẹkẹ́ lati pade rẹ̀, o si wipe, Alafia kọ?

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:19-26