Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Gehasi, iranṣẹ Eliṣa enia Ọlọrun na wipe, Kiyesi i, oluwa mi ti dá Naamani ara Siria yi si, niti kò gbà nkan ti o mu wá lọwọ rẹ̀: ṣugbọn, bi Oluwa ti mbẹ, emi o sare bá a, emi o si gbà nkan lọwọ rẹ̀.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:17-21