Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kó gbogbo Jerusalemu lọ, ati gbogbo awọn ijoye, ati gbogbo awọn alagbara akọni enia, ani ẹgbãrun igbèkun, ati gbogbo awọn oniṣọnà ati awọn alagbẹ̀dẹ: kò kù ẹnikan, bikòṣe iru awọn ti o jẹ talakà ninu awọn enia ilẹ na.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:7-20