Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu Jehoiakini lọ si Babeli, ati iya ọba, ati awọn obinrin ọba, ati awọn iwẹ̀fa rẹ̀, ati awọn alagbara ilẹ na, awọn wọnyi li o kó ni igbèkun lati Jerusalemu lọ si Babeli.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:10-20