Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kó gbogbo iṣura ile Oluwa lọ kuro nibẹ, ati iṣura ile ọba, o si ké gbogbo ohun-èlo wura wẹwẹ ti Solomoni ọba Israeli ti ṣe ni tempili Oluwa, bi Oluwa ti sọ.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:9-16