Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si rán Eliakimu, ti iṣe olori ile, ati Ṣebna akọwe, ati awọn àgba alufa, ti nwọn fi aṣọ ọ̀fọ bò ara, sọdọ Isaiah woli ọmọ Amosi.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:1-4