Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Hesekiah ọba gbọ́, o si fà aṣọ rẹ̀ ya, o si fi aṣọ ọ̀fọ bò ara rẹ̀, o si lọ sinu ile Oluwa.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:1-5