Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun u pe, Bayi ni Hesekiah wi, Ọjọ oni ọjọ wàhala ni, ati ti ibawi, ati ẹgàn: nitoriti awọn ọmọ de oju-ibí, kò si si agbara lati bi.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:1-8