Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn olori si wi fun wọn pe, Ẹ da wọn si: nwọn si di aṣẹ́gi ati apọnmi fun gbogbo ijọ; gẹgẹ bi awọn olori ti sọ fun wọn.

Joṣ 9

Joṣ 9:19-27