Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si pè wọn, o si wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ẹnyin fi tàn wa wipe, Awa jìna rére si nyin; nigbati o jẹ́ pe lãrin wa li ẹnyin ngbé?

Joṣ 9

Joṣ 9:16-27