Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi li awa o ṣe si wọn, ani awa o da wọn si, ki ibinu ki o má ba wà lori wa, nitori ibura ti a bura fun wọn.

Joṣ 9

Joṣ 9:19-22