Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn gbogbo awọn olori wi fun gbogbo ijọ pe, Awa ti fi OLUWA, Ọlọrun Israeli, bura fun wọn: njẹ nitorina awa kò le fọwọkàn wọn.

Joṣ 9

Joṣ 9:12-24