Yorùbá Bibeli

Joṣ 24:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si wi fun gbogbo awọn enia pe, Bayi ni OLUWA, Ọlọrun Israeli wi, Awọn baba nyin ti gbé ìha keji Odò nì li atijọ rí, ani Tera, baba Abrahamu, ati baba Nahori: nwọn si sìn oriṣa.

Joṣ 24

Joṣ 24:1-6