Yorùbá Bibeli

Joṣ 24:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

JOṢUA si pè gbogbo awọn ẹ̀ya Israeli jọ si Ṣekemu, o si pè awọn àgba Israeli, ati awọn olori wọn, ati awọn onidajọ wọn, ati awọn ijoye wọn; nwọn si fara wọn hàn niwaju Ọlọrun.

Joṣ 24

Joṣ 24:1-3