Yorùbá Bibeli

2. Sam 7:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi ọba si wọle lọ, o si duro niwaju Oluwa, o si wipe, Oluwa Ọlọrun, tali emi, ati ki si ni idile mi, ti iwọ fi mu mi di isisiyi?

2. Sam 7

2. Sam 7:13-24