Yorùbá Bibeli

2. Sam 7:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nkan kekere li eyi sa jasi li oju rẹ, Oluwa Ọlọrun; iwọ si sọ ti idile iranṣẹ rẹ pẹlu ni ti akoko ti o jina. Eyi ha ṣe ìwa enia bi, Oluwa Ọlọrun?

2. Sam 7

2. Sam 7:13-20