Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ọdun mejilelogun ni Ahasiah jẹ nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba; o si jọba li ọdun kan ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ a si ma jẹ Ataliah, ọmọbinrin Omri ọba Israeli.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:20-29