Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si rìn li ọ̀na ile Ahabu, o si ṣe ibi niwaju Oluwa, bi ile Ahabu ti ṣe: nitoriti o nṣe ana ile Ahabu.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:26-29