Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 7:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si dide li afẹ̀mọjumọ lati lọ si ibùdo awọn ara Siria: nigbati nwọn si de apa ti o kangun ibùdo Siria, kiyesi i, kò si ọkunrin kan nibẹ.

2. A. Ọba 7

2. A. Ọba 7:1-6