Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 7:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si yàn ijòye na, lọwọ ẹniti o nfi ara tì, lati ṣe itọju ẹnu bodè: awọn enia si tẹ̀ ẹ mọlẹ ni bodè, o si kú, bi enia Ọlọrun na ti wi, ẹniti o sọ̀rọ nigbati ọba sọ̀kalẹ tọ̀ ọ wá.

2. A. Ọba 7

2. A. Ọba 7:16-20