Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 7:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia si jade lọ, nwọn si kó ibùdo awọn ara Siria. Bẹ̃ni a ntà oṣùwọn iyẹ̀fun kikunná kan ni ṣekeli kan, ati oṣuwọn barle meji ni ṣekeli kan, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa.

2. A. Ọba 7

2. A. Ọba 7:9-20