Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikan si jade lọ si igbẹ lati fẹ́ ewebẹ̀, o si ri ajara-igbẹ kan, o si ka eso rẹ̀ kún aṣọ rẹ̀, o si rẹ́ ẹ wẹwẹ, o dà wọn sinu ikoko ipẹ̀tẹ na: nitoripe nwọn kò mọ̀ wọn.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:32-41