Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliṣa si tun pada wá si Gilgali, iyàn si mu ni ilẹ na; awọn ọmọ awọn woli joko niwaju rẹ̀: on si wi fun iranṣẹ rẹ̀ pe, Gbe ìkoko nla ka iná, ki ẹ si pa ipẹ̀tẹ fun awọn ọmọ awọn woli.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:31-42