Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iya ọmọ na si wipe, Bi Oluwa ti mbẹ, ati bi ẹmi rẹ ti mbẹ, emi kì o fi ọ silẹ. On si dide, o si ntọ̀ ọ lẹhin.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:20-34