Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun Gehasi pe, Di àmure rẹ, ki o si mu ọpa mi li ọwọ rẹ, ki o si lọ, bi iwọ ba ri ẹnikẹni li ọ̀na, máṣe ki i; bi ẹnikeni ba si kí ọ, máṣe da a li ohùn: ki o si fi ọpá mi le iwaju ọmọ na.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:19-37