Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gehasi si kọja siwaju wọn, o si fi ọpá na le ọmọ na ni iwaju, ṣugbọn kò si ohùn, tabi afiyesi: nitorina o si tun pada lati lọ ipade rẹ̀, o si wi fun u pe, Ọmọ na kò ji.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:28-36