Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati gbogbo awọn ọkunrin ọlọla, ẹ̃dẹgbãrin, ati awọn oniṣọnà ati awọn alagbẹdẹ ẹgbẹrun, gbogbo awọn ti o li agbara ti o si yẹ fun ogun, ani awọn li ọba Babeli kó ni igbèkun lọ si Babeli.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:14-17