Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoiakini ọba Juda si jade tọ̀ ọba Babeli lọ, on, ati iya rẹ̀, ati awọn iranṣẹ rẹ̀, ati awọn ijoye rẹ̀, ati awọn iwẹfa rẹ̀: ọba Babeli si mu u li ọdun kẹjọ ijọba rẹ̀.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:7-18