Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao-Neko si fi Eliakimu ọmọ Josiah jẹ ọba ni ipò Josiah baba rẹ̀, o si pa orukọ rẹ̀ dà si Jehoiakimu, o si mu Jehoahasi kuro; on si wá si Egipti, o si kú nibẹ.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:31-37