Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao-Neko si fi i sinu idè ni Ribla, ni ilẹ Hamati, ki o má ba jọba ni Jerusalemu; o si fi ilẹ na si abẹ isìn li ọgọrun talenti fadakà, ati talenti wura.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:32-37