Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoiakimu si fi fadakà ati wura na fun Farao; ṣugbọn o bu owo-odè fun ilẹ na lati san owo na gẹgẹ bi ofin Farao: o fi agbara gbà fadakà ati wurà na lọwọ awọn enia ilẹ na, lọwọ olukuluku gẹgẹ bi owo ti a bù fun u, lati fi fun Farao-Neko.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:31-37