Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹlu gbogbo ile ibi-giga wọnni ti o wà ni ilu Samaria wọnni, ti awọn ọba Israeli ti kọ́ lati rú ibinu Oluwa soke ni Josiah mu kuro, o si ṣe si wọn gẹgẹ bi gbogbo iṣe ti o ṣe ni Beteli.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:13-20