Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Jọwọ rẹ̀; máṣe jẹ ki ẹnikan ki o mu egungun rẹ̀ kuro. Bẹ̃ni nwọn jọwọ egungun rẹ̀ lọwọ, pẹlu egungun woli ti o ti Samaria wá.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:13-27