Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o wipe, Ọwọ̀n isa-okú wo li eyi ti mo ri nì? Awọn enia ilu na si sọ fun u pe, Isà-okú enia Ọlọrun nì ni, ti o ti Juda wá, ti o si kede nkan wọnyi ti iwọ ti ṣe si pẹpẹ Beteli.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:8-26