Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati nwọn kọja tan, ni Elijah wi fun Eliṣa pe, Bère ohun ti emi o ṣe fun ọ, ki a to gbà mi kuro lọwọ rẹ. Eliṣa si wipe, Emi bẹ̀ ọ, jẹ ki ìlọ́po meji ẹmi rẹ ki o bà le mi.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:2-16