Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Elijah si mu agbáda rẹ̀, o si lọ́ ọ lù, o si lù omi na, o si pin wọn ni iyà sihin ati sọhun, bẹ̃ni awọn mejeji si kọja ni ilẹ gbigbẹ.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:4-13