Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Iwọ bère ohun ti o ṣoro: ṣugbọn, bi iwọ ba ri mi nigbati a ba gbà mi kuro lọdọ rẹ, yio ri bẹ̃ fun ọ; ṣugbọn bi bẹ̃ kọ, kì yio ri bẹ̃.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:5-16