Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Elijah si wi fun u pe, Eliṣa, emi bẹ̀ ọ, joko nihinyi; nitori ti Oluwa rán mi si Jeriko. On si wipe, Bi Oluwa ti mbẹ, ati bi ẹmi rẹ ti mbẹ, emi kì o fi ọ silẹ. Bẹ̃ni nwọn de Jeriko.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:1-7