Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ awọn woli ti mbẹ ni Beteli jade tọ̀ Eliṣa wá, nwọn si wi fun u pe, Iwọ ha mọ̀ pe Oluwa yio mu oluwa rẹ lọ kuro li ori rẹ loni? On si wipe, Bẹ̃ni, emi mọ̀, ẹ pa ẹnu nyin mọ́.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:1-11