Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ awọn woli ti mbẹ ni Jeriko tọ̀ Eliṣa wá, nwọn si wi fun u pe, Iwọ ha mọ̀ pe Oluwa yio mu oluwa rẹ lọ kuro li ori rẹ loni? On si dahùn wipe, Bẹ̃ni, emi mọ̀, ẹ pa ẹnu nyin mọ́.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:1-15