Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi nwọn ti nlọ, ti nwọn nsọ̀rọ, si kiyesi i, kẹkẹ́ iná ati ẹṣin iná si là ãrin awọn mejeji; Elijah si ba ãjà gòke re ọrun.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:7-17