Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliṣa si ri i, o si kigbe pe, Baba mi, baba mi! kẹkẹ́ Israeli, ati awọn ẹlẹṣin rẹ̀. On kò si ri i mọ: o si di aṣọ ara rẹ̀ mu, o si fà wọn ya si meji.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:5-14