Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ni yio si ṣe àmi fun ọ, Ẹ jẹ ilalẹ̀hu li ọdun ni, ati li ọdun keji eyiti o hù ninu ọkanna; ati li ọdun kẹta ẹ fun irúgbìn, ki ẹ si kore, ki ẹ si gbìn ọgba ajara, ki ẹ si jẹ eso rẹ̀.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:26-31