Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ikánnu rẹ si mi ati irera rẹ de eti mi, nitorina li emi o fi ìwọ̀ mi kọ́ ọ ni imu, ati ijanu mi si ẹnu rẹ, emi o si yi ọ pada si ọ̀na na ti iwọ ti ba wá.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:22-33