Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi li ọ̀rọ ti Oluwa ti sọ niti rẹ̀; Wundia ọmọbinrin Sioni ti kẹgàn rẹ, o si ti fi ọ rẹrin ẹlẹyà; ọmọbinrin Jerusalemu ti mì ori rẹ̀ si ọ.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:16-22