Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tani iwọ sọ̀rọ buburu si ti iwọ si kẹgàn? ati tani iwọ gbé ohùn rẹ si òke si, ti iwọ gbé oju rẹ ga si òke? ani si Ẹni-Mimọ Israeli.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:15-30