Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Isaiah ọmọ Amosi ranṣẹ si Hesekiah wipe, Bayi li Oluwa Ọlọrun Israeli wi pe, adura ti iwọ ti gbà si mi si Sennakeribu ọba Assiria emi ti gbọ́.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:14-25