Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹniti Oluwa ti ba dá majẹmu, ti o si ti kilọ fun wọn, wipe, Ẹnyin kò gbọdọ bẹ̀ru awọn ọlọrun miran, bẹ̃ni ẹnyin kò gbọdọ tẹ̀ ara nyin ba fun wọn, tabi ki ẹ sìn wọn, tabi ki ẹ rubọ si wọn:

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:28-36