Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Titi di oni yi nwọn nṣe bi iṣe wọn atijọ: nwọn kò bẹ̀ru Oluwa, bẹ̃ni nwọn kò ṣe bi idasilẹ wọn, tabi ilàna wọn, tabi ofin ati aṣẹ ti Oluwa pa fun awọn ọmọ Jakobu, ti o sọ ni Israeli;

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:26-41