Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ọba Assiria paṣẹ, wipe, Ẹ mu ọkan ninu awọn alufa ti ẹnyin ti kó ti ọhún wá lọ sibẹ; ẹ si jẹ ki wọn ki o lọ igbe ibẹ, ki ẹ si jẹ ki o ma kọ́ wọn ni iṣe Ọlọrun ilẹ na.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:24-33